Bo tilẹ jẹ pe jiji kirun laarin oru wa lara ohun to yẹ ki Musulumi maa ṣe tẹlẹ ki Ramadan to o de, sibẹ, ẹkọ ẹsin Islam ni pe o tun ṣe pataki pupọ ninu oṣu Ramadan lati ...